Honourable Azeez Adeoye to ti figba kan ri jẹ kanselọ Olufọn Ward 8 niluu Ifọn Ọṣun nijọba ibilẹ Orolu nipinlẹ Ọṣun lo ti gbẹmi mi bayii ninu wahala tuntun to bẹ silẹ laarin ilu naa ati Ilobu.
Gbagede gbọ pe laarọ oni Furaidee ni ibọn ba ọkunrin naa, nigba ti wọn yoo si fi gbe e de UNIOSUNTH niluu Osogbo, o ti jade laye.
Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ....
No comments:
Post a Comment