IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 13 February 2025

Laide Bakare di Aarẹ Yeye-Oge ti ilu Ẹdẹ


Gbogbo eto lo ti to bayii lati fi oṣere tiata ilẹ wa nni, Ọlaide Bakare jẹ Aarẹ Yeye-Oge ti ilu Ẹdẹ nipinlẹ Ọṣun.


Ọjọ kẹrinla oṣu keji ọdun yii ni Timi ilu Ẹdẹ, Ọba Munirudeen Adeṣọla Lawal, yoo fi obinrin to jẹ ọkan lara awọn oluranlọwọ pataki fun Gomina Ademọla Adeleke ọhun joye laafin rẹ.



No comments:

Post a Comment