Gomina ipinlẹ Ọyọ Ẹnjinia Ṣeyi Makinde, ti kede Ọmọọba Abimbọla Akeem Ọwọade, gẹgẹ bii Alaafin tuntun fun ilu Ọyọ.
No comments:
Post a Comment