IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 26 January 2025

Baalẹ Eṣu niluu Oṣogbo, Oloye Kayọde Eṣuleke ti ku o

 

Oloye Dokita Ọmọkayọde Idowu Eṣuleke la gbọ pe o ti jade laye lalẹ ọjọ Satide, ọjọ karundinlọgbọn oṣu kinni ọdun yii.

Ẹni ọdun mẹrinlelọgọrin ni baba ti awọn eeyan tun maa n pe ni The Boy naa.

Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ

No comments:

Post a Comment