IROYIN YAJOYAJO

Friday, 6 December 2024

Sultonul Wahizeen ilẹ Yoruba, Sheikh Muyideen Ajani Bello, ti jade laye


Oniwaasi agbaye nni, Sheikh Muyideen Ajani Bello ni wọn ti kede pe o ti jade laye bayii.


 Ọkan lara awọn ọmọlẹyin baba yii, Sheikh Akeugbagold Taofeeq, lo kede iku Baba Ajani.


Ọmọ ọdun mẹrinlelọgọrin ni baba naa ko too jade laye, manigbagbe si ni igbesi aye baba ti waasi rẹ jalejako naa.

No comments:

Post a Comment