Wọn ti kede iku iyawo akọkọ fun onkọwe ati oṣere tiata nni, Oloye Peter Fatomilọla.
Ọsan oni, Wẹsidee, ogunjọ oṣu kọkanla, la gbọ pe iya naa, Rev. (Mrs) Adebọla Fatomilọla, jade laye nileewosan Jẹnẹra niluu Ileefẹ.
Ọmọbibi ipinlẹ Ekiti ni mama, o si lo ọdun mẹtadinlọgọrin loke eepẹ ko too dagbere faye.
No comments:
Post a Comment