IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 6 November 2024

Erin Wo! Taoreed Lagbaja ti ku o

 


Olori awọn ọmọ ileeṣẹ ologun ilẹ wa, Lt. General Taoreed Abiọdun ti jade laye.

Oluranlowo pataki fun Aare Tinunu lori eto iroyin, Bayo Onanuga lo kede rẹ laipẹ yii.

Ọnanuga sọ pe alẹ ọjọ Tusidee ọsẹ yii lọkunrin omobibi ilu Ilobu naa jade laye lẹni ọdun merindinlogota.

O ni Aare Tinubu ba idile re ati ileese ologun ilẹ wa kẹdun iku ọkunrin naa.

No comments:

Post a Comment