IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 12 September 2024

Erin wo! Ọwa Obokun ilẹ Ijeṣa ti waja!


Ọwa Obokun ilẹ Ijẹṣa, Ọba Gabriel Adekunle Aromọlaran, ti waja. 

Irọlẹ ọjọ Wẹsidee, ọjọ kọkanla oṣu kẹsan ni baba naa waja. 

Ẹni ọdun mẹtadinlaadọrun ni, o si lo ọdun mejilelogoji lori itẹ awọn babanla rẹ. 

Iwadi fihan pe wọn ti bẹrẹ eto gbogbo lati kede iku baba rẹ.

8 comments:

  1. May his soul rest in peace 🙏

    ReplyDelete
  2. May his gentle soul rest in peace amen.

    ReplyDelete
  3. May his soul rest in peace

    ReplyDelete
  4. May Kabiyesi soul rest in peace.

    ReplyDelete
  5. May HIS soul continue to rest in peace

    ReplyDelete
  6. May his soul rest in peace

    ReplyDelete
  7. May his soul rest in peace.

    ReplyDelete
  8. His soul SHALL rest in perfect peace IJMN AMEN
    Arc. Bashir Ayinde

    ReplyDelete