IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 12 September 2024

Erin wo! Ọba nla waja l'Ọṣun


Ọba nla kan lapa Ila-Oorun ipinlẹ Ọṣun la gbọ pe o ti waja bayii.

Bo tilẹ jẹ pe igbesẹ ti bẹrẹ lọwọ, eleyii ti wọn n pe ni 'oro', sibẹ ko tii si ikede lati aafin lori iku naa.

Ana, ọjọ Wẹsidee la gbọ pe ọba alaye naa waja.

Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ....

No comments:

Post a Comment