Aare orileede yii, Mohammadu Buhari ti sapejuwe iku eni to je gomina tele funpinle Kaduna, Lawal Kaita gege bii adanu nla forileede yii lapapo.
Kaita lo ku nirole ojoo Tusde sileewosan kan nilu Abuja leyin aisan to se e.
Buhari ninu oro ibanikedun ti akowe iroyin re, Sheu Garba fowosi so pe oniwatutu bii adaba, eni to see fokantan ni oloogbe naa to tun je omo egbe oselu APC.
Aare waa gbadura pe ki Olorun tu awon eeyan ipinle Kaduna ati Katsina ninu lori iku Kaita.
No comments:
Post a Comment