Senken ni inu obinrin olorin emi nni, Tope Alabi ti gbogbo eeyan mo si Agbo Jesu pelu awon molebi re n dun lojoo Tisde to koja lasiko to n si ile alarabara to sese ko pari.
Agbegbe Fagba ni Iju la gbo pe ile to fi odun meji ko sori ile pilooti meji ohun wa.
Pasito Femi Emmanuel ti ijo Living Spring Chapel la gbo pe o koko ya ile ohun si mimo lojo naa ki awejewemu too bere ni pereu.
No comments:
Post a Comment