Nitori idibo gomina Ọṣun, awọn ẹgbẹ oṣelu ṣepade pẹlu ajọ eleto idibo atileeṣẹ ọlọpaa
Njeetigbo
12:37
Ni imurasilẹ fun idibo gomina ipinlẹ Ọṣun ti yoo waye lọjọ kẹẹẹdogun, oṣu Kẹjọ, ọdun 2026, awọn ẹgbẹ oṣelu to lorukọ labẹ 'The Democrats...
Iroyin igbadegba