Irọ ni o! Mi o gbe ẹgbẹ oṣelu APC lọ si kootu o - Ajagunla Njeetigbo 15:23Sẹnetọ to n sọju awọn eeyan Aaringbungbun Ọṣun nile igbimọ aṣofin agba lorileede yii, Sẹnetọ Fadeyi Ajagunla, ti sọ pe ko si ootọ ninu ahesọ... Kaa Siwaju
L'Ọṣun, ori ko alaga ẹgbẹ Accord yọ lọwọ awọn agbebọn Njeetigbo 10:07 Titi di bi a ṣe n kọroyin yii, ileewosan UNIOSUNTH ni alaga ẹgbẹ Accord funjọba ibilẹ Oṣogbo, Hon. Asimiyu Ajibọla, ẹni ti gbogbo eeyan mọ ... Kaa Siwaju
O doju ẹ! Wọn ti ji aburo Adelabu Pẹnkẹlẹmẹsi gbe n'Ibadan o Njeetigbo 11:25Nnkan bii aago meje aabọ aarọ oni Wẹsidee, ọjọ Kẹta, oṣu kẹfa la gbọ pe awọn agbebọn da mọto Arabinrin Busayọ Adegoke duro lagbegbe Challeng... Kaa Siwaju
Wọn ti sinku ọkan lara awọn ọlọpaa ti onimọto kan pa lọjọ ọdun Ileya l'Ọṣun Njeetigbo 21:51Iṣẹlẹ buburu ọhun la gbọ pe o ṣẹlẹ niluu Oogi loju ọna Ọdeomu si Oṣogbo nirọlẹ ọjọ ọdun Ileya gan an. Ori ọkada ni awọn ọlọpaa mejeeji ọhun;... Kaa Siwaju
Ajagunla fẹsun kan ẹgbẹ APC Ọṣun, o ni inu otẹẹli ni wọn ti n kọ esi idibo Njeetigbo 12:57Sẹnetọ to n ṣoju awọn eeyan Aaringbungbun Ọṣun nile igbimọ aṣofin agba lorileeee yii, Sẹnetọ Fadeyi Olubiyi Ajagunla, ti sọ pe oun ko faramọ... Kaa Siwaju
2027: APC Ọṣun sọ Ajagunla di ọmọ orukan, o wọle tan, ko le jade mọ Njeetigbo 10:04Laarin awọn aṣofin ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP tẹlẹ ti wọn darapọ mọ ẹgbẹ APC l'Ọṣun, Sẹnetọ Ajagunla Fadeyi Olubiyi nikan ni ko ri tikẹẹti gba l... Kaa Siwaju
Awọn ọmọ ẹgbẹ Accord niluu Mọdakẹkẹ ṣeleri atilẹyin fun Oyedọtun Njeetigbo 13:35Awọn ọmọ ẹgbẹ Accord niluu Mọdakẹkẹ ti ṣeleri lati duro ti ọkan lara wọn, Samuel Oyedọtun, ẹni to n dije lati gba tikẹẹti ẹgbẹ naa fun ipo ... Kaa Siwaju
2027: Idi ti a fi ṣeleri atilẹyin fun Sam Oyedọtun - Ijeṣa Unites Njeetigbo 21:53Ẹgbẹ kan ti ko ni nnkan ṣe pẹlu oṣelu nilẹ Ijeṣa, Ijeṣa Unites, ti ṣeleri lati ṣatilẹyin fun erongba Hon. Sam Oyedọtun lati dije funpo ile i... Kaa Siwaju
2027: Gbogbo awọn oludije lati Iwọ-Oorun Ọṣun gba lati ṣatilẹyin fun Ogunbiyi Njeetigbo 16:21Gbogbo awọn to gba fọọmu ẹgbẹ APC lati dije funpo sẹnetọ ni iha Iwọ-Oorun Ọṣun la gbọ pe wọn ti fohun ṣọkan lati ṣatilẹyin fun Dokita Akin ... Kaa Siwaju
Dokita Oluṣẹgun Ọṣọba ti ku o Njeetigbo 21:47Ọkan lara awọn to kọ iwe ofin orileede Naijiria lọdun 1976, Dokita Samuel Oluṣẹgun Ọṣọba, ti jade laye. Ninu ile rẹ niluu Ijẹbu-Ode la gbọ p... Kaa Siwaju
Ṣe ẹ ti gbọ nnkan to ṣẹlẹ si akẹkọọ to pegede julọ ni Fasiti Imọ-ẹrọ niluu Ogbomọṣọ? Njeetigbo 21:54Oludije funpo gomina ipinlẹ Ọṣun labẹ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, Alhaji Bọla Oyebamiji, ti fun akẹkọọ to pegede julọ ni Ladoke Ak... Kaa Siwaju
Adeleke rọ Apetumodu loye Njeetigbo 17:41Gomina Ademọla Adeleke ti rọ Apetumodu ti ilu Ipetumodu, Ọba Joseph Oloyede, loye. Oni, ọjọ Aje, ọjọ Kọkanla, oṣu Karun nijọba gbe igbesẹ na... Kaa Siwaju
Bi Gomina Adeleke ko ba tiẹ lẹ posita kankan, irọrun ni idibo oṣu Kẹjọ yoo jẹ fun un - Oyewumi Njeetigbo 09:28Alakoso Agba fun igbimọ ipolongo ibo saa keji fun Gomina Ademọla Adeleke, Sẹnetọ Lere Oyewumi, ti fi ọwọ mejeeji sọya pe, lai si rogbodiyan ... Kaa Siwaju
Ibi ti mo gbe iṣẹ idagbasoke Ọṣun de lọdun 2018 ni Najeem Salaam ti maa bẹrẹ - Arẹgbẹṣọla Njeetigbo 08:50Akọwe apapọ ẹgbẹ oṣelu African Democratic Congress, Ọgbẹni Rauf Adesọji Arẹgbẹṣọla, ti fi da awọn eeyan ipinlẹ Ọṣun loju pe wọn ko nii kabam... Kaa Siwaju
Ki lo n ṣẹlẹ laafin Ọwamiran ti ilu Ẹsa-Oke? Njeetigbo 18:27Iroyin to n wa lati ilu Ẹsa Oke nipinlẹ Ọṣun ko fini lọkan balẹ rara. Ohun ti a gbọ ni pe awọn oloye ilu naa ti kede konilegbele lọsan oni W... Kaa Siwaju