O doju ẹ! Lẹyin wakati marun, wọn ko bẹrẹ idibo IPAC l'Ọṣun Njeetigbo 14:37Titi di asiko ti a n koroyin yii jọ, wọn ko tii bẹrẹ idibo igbimọ awọn alaga ẹgbẹ oṣelu, IPAC, to yẹ ko waye nipinlẹ Ọṣun. Idibo naa ni wọn ... Kaa Siwaju
Igbimọ Agba Ọṣun dawọọdunnu pẹlu Adewọle ati Adejare lori iyansipo wọn Njeetigbo 18:13Alaga Igbimọ Agba Ọṣun labẹ ẹgbẹ oṣelu APC, Ẹnjinia Ṣọla Akinwumi, ti ranṣẹ ikini ku oriire si Ọjọgbọn Isaac Adewọle ati Ọnarebu Adejare Bel... Kaa Siwaju
Gbajugbaja oniṣowo niluu Oṣogbo nni, Ọmọọba Ọbẹlawọ, ti jade laye Njeetigbo 21:27Ọmọọba Lawal Ọbẹlawọ, to jẹ gbajugbaja onisowo niluu Oṣogbo, ni wọn ti sọ pe o jade laye bayii. Inu oṣu karun ọdun yii ni baba naa i ba pe ọ... Kaa Siwaju
Ọtun Balogun ilu Mọdakẹkẹ, 'Coach' Onigbinde, ti ku o Njeetigbo 05:23Ọmọ orileede Naijiria to kọkọ jẹ Olukọ ẹgbẹ agbabọọlu ilẹ wa nni, Super Eagles, Oloye Festus Adegboye Onigbinde, ti jade laye. Alẹ ọjọ Mọnde... Kaa Siwaju
Sẹnetọ Lere Oyewumi darapọ mọ ẹgbẹ Accord Njeetigbo 17:22Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan Iwọ-Oorun Ọṣun nile igbimọ aṣofin agba, Sẹnetọ Lere Oyewumi, ti darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu ACCORD bayii. Oyewumi, ẹni ... Kaa Siwaju
Da tiẹ mọ! Orukọ awọn gomina atigbakeji wọn fun idibo oṣu Kẹjọ l'Ọṣun ti jade o Njeetigbo 15:37 Kaa Siwaju
Adejare Bello di alaga igbimọ alakoso Fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ, Ileefẹ Njeetigbo 12:41Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu la gbọ pe o ti yan aṣoju orileede yii ni United Mexican States tẹlẹ, Anbasadọ Rafiu Adejare Bello, gẹgẹ bii alaga igb... Kaa Siwaju
Sunday Bisi ko lagbara lati sọrọ lorukọ ẹgbẹ PDP, ṣe lo n tan Adeleke - Bamidele Njeetigbo 18:51Akọwe igun ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party nipinlẹ Ọṣun, Ṣeyi Bamidele, ti sọ pe ofuutufẹẹtẹ, ofo ọjọkeji ọja ni aṣẹ ti alaga igun keji ... Kaa Siwaju
O ma ṣe o! Ọkan lara awọn ibeji olorin ẹmi nni, Adegbodu Twins, ti jade laye Njeetigbo 06:51Taiwo Adegbodu, ọkan lara awon ibeji akọrin ẹmi ti wọn n jẹ Adegbodu Twins JP ti jade laye. Ninu ọrọ ti ekeji rẹ fi sori feesibuuku nidaji ọ... Kaa Siwaju
Osun 2026: Ojuṣe gbogbo wa ni aṣeyọri Bọla Oyebamiji - APC sọ fawọn ọmọ ẹgbẹ Njeetigbo 23:31Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress lẹkun Iwọ-oorun Ọṣun ti ke si gbogbo awọn ọmọ ẹgbẹ lati mọ pe agbajọwọ ni aṣeyọri idibo gomina ti yoo w... Kaa Siwaju
Adeleke kede igba ti awọn olukọ tuntun yoo bẹrẹ iṣẹ l'Ọṣun Njeetigbo 15:17Gomina Ademọla Adeleke ti kede pe iṣi-kinni awọn olukọ tuntun tijọba oun gba yoo bẹrẹ iṣẹ lọjọ kinni, oṣu Kẹta ọdun yii. Ninu atẹjade kan ti... Kaa Siwaju
INEC sun ọjọ idibo gomina ipinlẹ Ọṣun siwaju Njeetigbo 22:01Ajọ eleto idibo ilẹ wa, INEC, ti sun ọjọ idibo gomina ipinlẹ Ọṣun siwaju. Ọjọ kẹjọ, oṣu kẹjọ, ọdun yii ni wọn kọkọ kede fun idibo naa tẹlẹ, ... Kaa Siwaju
Ayẹwo awọn oṣiṣẹ: Opurọ ni ileeṣẹ Sally Tibbot, a n reti awọn ajọ EFCC ati ICPC lati taṣiri etekete awọn APC yii - Alimi Njeetigbo 14:56Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti sọ pe ko si ootọ kankan ninu ariwo ipaṣipayọ owo oṣu to to biliọnu lọna mẹtala naira ti ileeṣẹ ayẹwe-owo wo, Sally Tibb... Kaa Siwaju
Nitori aawẹ, Gomina Adeleke din asiko iṣẹ ku fun awọn oṣiṣẹ ijọba Njeetigbo 16:04Lati le mu nnkan rọrun fun awọn Kristiẹni atawọn Musulumi ti wọn jẹ oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Ọṣun, Gomina Ademọla Adeleke ti din asiko iṣẹ wọn ku ... Kaa Siwaju
Igbimọ Agba Ọṣun ṣepade pẹlu Oyebamiji, wọn ranṣẹ si gbogbo awọn ti wọn jọ dije Njeetigbo 22:22Igbimọ Agba Ọṣun ninu ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress ti ke si gbogbo awọn to du tikẹẹti gomina ninu ẹgbẹ naa lati ṣiṣẹ papọ pẹlu oludi... Kaa Siwaju